ORIYOMI HAMZAT TI TU ASIRI TO WA LARIN OUN ATI GOMINA SEYI MAKINDE
ORIYOMI HAMZAT TI TU ASIRI TO WA LARIN OUN ATI GOMINA SEYI MAKINDE Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́ Alaye re nípa ikú ọ̀dọ́bìnrin Mary Habila, òṣíṣẹ́ Mínísítà David Umahi tí wọ́n ló kú sílé rẹ̀ Ojú wọn re o, aseeyan lole, Ìjọba fojú mẹ́ta lára àwọn afurasí agbésùnmọ̀mí tó lọwo nínú ikọlu ijinigbe isekupani tàwọn akẹkọọ áti oluko nijọba ibile Oríre l'Ogbomoso hàn nílé ẹjọ́ * Oga agba ọlọ́pàá Naijiria ti kilo fún àwọn ọmọ Nàìjíríà pelu bí wọn ṣe ni àwọn amokun seka tí ń kó ohun ìjà wọlé láti apá àríwá wá sí gúúsù Naijiria Ọmọ ní wike òkúró ní tábà rí mọ, Aarẹ Tinubu gbóríyìn fún Wike pelu orisirisi ìṣe àkànṣe àti ìdàgbàsókè to ń ṣe ní Abuja * Oga agba ọlọ́pàá Naijiria ti sedaro ọlọ́pàá to pàdánù ẹ̀mí rẹ nínú ìṣe idoola ni ipinlẹ Oyo, ó wá gbosuba kaare fún gbogbo àwọn tó kopa ninu ise naa * Níbi àwọn ọmọ ile eko Mussa ni ipinlẹ Borno ṣe pé ọjọ́ kẹrìnlélọ́gọ́ta loni, àwọn ará agbegbe na ké sí ìjọba láti sọ̀rọ̀ kí wọ́n sì gbé gbèsè idoola àwọn ọmọ naa T'ẹgbon taburo lemi ati Gómìnà Makinde o bakan náà ọrẹ at'ọrẹ ni wa nítori náà kosija láàrin wa Oriyọmi Hamzat lo bẹ. * Ileṣẹ ọlọ́pàá ìpínlẹ̀ Bayelsa tí fi panpe òfin gbé àwọn òṣìṣẹ́ ilese ìjọba mẹta pelu esun jíjí ohun ìní ijoba ti iye rẹ too eedegbeta milionu naira * Oga ilé ìwé kan dero ago ọlọ́pàá lẹ́yìn tó lu ọmọ ọdún méjìlá kan pá ni ipinlẹ Anambra * Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun ti tako ẹ̀sùn tí ẹgbẹ́ òṣèlú APC fi kàn wọn pé wọn ò ṣe òpópónà Iwo Township Road tí wọ́n sese sì daada, wọ́n ni kenu má gbofo lásán ni ọrọ naa

LATEST & TRENDING NEWS FOR THE DAY...IROYIN AKOJOPO AGBEYEWO LORI YBN..NIGERIA & YORUBA NATION NEWS

France vs. England Highlights FIFA World Cup 2026 | Sportschau

(Kashim) Shettima Used to be a Reporter for Me - Sowore

PEOPLE WHO KIDNAPPED US WERE NOT BANDITS, OYO TEACHER NARRATES 56-DAYS IN CAPTIVITY.

BASKETMOUTH TEARS DOWN LAUGH FACTORY

SEYI MAKINDE IS PLAYING GAMES WITH OYO'S SECURITY! – AGBAAKIN SPEAKS OUT

Anchor Media የደጋ ዳሞቱ ጦርነት፥ 4 ጄነራሎችና 7 ኮሎኔሎች፥ የተዋከበው የምክክር መድረክ፥ የብልጽግናው የተጋሩ ሰልፍ፥ የአሜሪካን ስንዴ ለኢትዮጵያ

KOLA OLOOTU TU GBOGBO ASIRI GAME PLAN IJINIGBE AWON AKEKOO ATI OLUKO TO SELE NI ORIIRE, OGBOMOSO

She Sold Fish to Make Him a Lawyer... He Sued Her for Divorce.

OPC LO KOGUN JA ILE YORUBA ASIRI TU/ NORTH FARIGA TORI TINUBU FEPIN NAIJA/ EFI IGBOHO LORUN SILE

My husband sold me and his two children to aboki gold seller // #thejuis

How Sunday Igboho Escaped DSS/Army Raid - Eye Witness Recounts!!!

Spain defeats Argentina in World Cup championship

Scientists Finally Solved The Yoruba DNA Mystery — After 500 Years

HA! OLUKO TI WON JIGBE NI ORIIRE TU PEREPERE, AWON TE GBO RI NIPA OHUN TO SELE GAN..OGBENUTAN

IKILO NLA REE FUNN GOV. MAKINDE LORI ORO IGBOHO ATI TINUNBU!!

MAKINDE FORUKO AWON EEYAN MARUN TO PADANU EMI WON LASIKO TI WON FE DOOLA AWON AKEKOO ORIIRE,OGBOMOSO

NEWS UPDATE ON AYEWA. AMONA. MIDE MARTINS AJIRAN FAMILY

ALFA LANDLORD DOMI BACK TO BACK AMO LEYIN NA MI O GBADUN AYE MI#kokoroalate #oriyomihamzat #news

