KI AYA AARE SI IGBA AKARA,KULIKULI ATI AGBADO FUN AWON MOLEBI RE NAA - AGBEJORO KAN WOJU REMI TINUBU
KI AYA AARE SI IGBA AKARA,KULIKULI ATI AGBADO FUN AWON MOLEBI RE NAA - AGBEJORO KAN WOJU REMI TINUBU Ileṣẹ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Rivers ti mú afurasi ọdaran kan tó fi ìbọn pamọ sínú búrẹ́dì lakoko to n rinrin àjò ni Ipinle naa Ileṣẹ èso alaabo èso ara ẹni labolu tí fi panpe òfin gbé oluko ilé ẹ̀kọ́ ijoba kan ni Ipinle Kwara fún esun fífún ọmọ ilé ìwé alakobere ọmọ ọdún mẹ́rìnlá kan lóyún Ijoba apapo orile-ede Naijiria lábẹ́ isejoba Aare Tinubu tí bù wolu òfin nọ́mbà idanimo lójú òpó ayélujára Atenuje ṣàkóbá fun ikọ olopaa kan o fun bi o se gbenusi Hennessy lenu ise ti won fi mu fídíò re ju sigboro aye. Alága Ìjọba ibilẹ Talata Mafara, Yahaya Yari bu sekun nita gbangba lakoko tí wọn ṣe ìsìnkú èèyàn meedogun to dagbere fàyè nínú ikọlu àwọn jànduku Kí aya Aare sì gba àkàrà, kuli kuli, àti àgbàdo fún àwọn molebi rẹ náà kì àwọn ọmọ Naijiria lè mọ pe olere lórí looto, Agbẹjọ́rò Inibehe Effiong lo gbéna woju Aya Aarẹ bee Wiwo la o wo o, gbogbo ile ti o ba lesenle di wiwo nipinlẹ Eko eyí jeyo fun bu Ìjọba se ti bẹ̀rẹ̀ sí í wó àwọn ilé tó ti rẹ̀ nítòsí èyí tó wo pa èèyàn mẹ́sàn-án l'Eko Oluwo ti ilẹ̀ Ìwó, Ọba Abdulrosheed Adewale Akanbi tí gbóríyìn fún àwọn imamu apá Gúúsù Ìwọ̀ Oòrùn Naijiria fún igbésẹ̀ fífi orúkọ sílẹ̀ lábé ijoba Mínísítà fún Ọ̀rọ̀ Ilé ni Nàìjíríà, Olubunmi Tunji-Ojo, tí ṣàlàyé bí wọn ṣe mú àwọn olórí janduku ni papako òfurufú ni Ipinle Katsina

BI A O SE DOOLA AWON AKEKOO ATI AWON OLUKO TI AWON AJINIGBE JIGBE NI O JE MI LOGUN MAKINDE SORO SOKE

ATOTO ARERE: BÁYÌÍ NI ÀWỌN ỌMỌ NÀÌJÍRÍÀ ṢE BÍNÚ TÁN

South Africa Economy Losing Millions after Foreigners Protest mostly Nigeria & Ghana

SUNDAY IGBOHO VS GANI ADAMS - TANI DAGBORU

NKAN DE!! WON TUN JI AWON OMO ILE TO SE IDANWO NECO LO…OLORI BANDIT NI BOYS OUN NI AWON OMO OLOGUN

Why Did Accord EXCO Fall Out With Oriyomi Hamzat? | ACCORD SECRETARY speaks

Seriake Dickson Speaks On NDC Registration Status, Legal Battles + More | Sunday Politics

LAGOS International Airport MM NEW Departure Protocol 2026 | Before You Fly, Watch This

ASIRI OMOSE KAN TO TAN OGA RE PA NIPINLE KWARA TI TU BAYI O LORO BA BEYIN YO

SE GANI ADAMS FEPA IGBOHO BIOSEPA FASHEUN NI? / REMI TINUBU ALAKARA & KULIKULI

Inside Iran: Senior official sits down with NewsNation for an exclusive interview | FRONTLINES

AWON OLOPA PA BANDIT AJINIGBE MERIN…WON PA OLORI MIYATTI ALLAH…GBOGBO AJINIGBE TOWO BA PIPA NI BAYI

AWON AREWA ATI FULANI KAN WOJU SUNDAY IGBOHO NI IGBOHO NA BA FARAYA DAPADA FUN NI GBIGBONA

AARE TINUBU TI KEDE IGBESE TUNTUN LATI DOOLA AWON AKEKOO ATI OLUKO TI WON JI GBE NI OGBOMOSO

AWON AGBAGBA ILE YORUBA TI KAN GANI ADAMS NI ABUKU NLA !! OGA OO!!

Senegal Shocked The World & Destroyed England 😱🔥⚡ ❮ Senegal (3-1) England ❯ | Historic Comeback

WON SA OKO MI LADAA LORI ATI LORUN KA LE KURO NILU - ESNAT LO SO OHUN OJU RI NILE SOUTH AFRICA

Winning Drive Service with Covenant House Chapel

Sunday Morning, 28 June 2026

