LEYIN ITUSILE AWON AKEEKO ATI OLUKO TI WON JIGBE NI OGBOMOSO - IJOBA SEYI MAKINDE BA SE BEBE
LEYIN ITUSILE AWON AKEEKO ATI OLUKO TI WON JIGBE NI OGBOMOSO - IJOBA SEYI MAKINDE BA SE BEBE Ayo ń lá ni idoola àwọn tó wà nigbekun jẹ́ ṣùgbọ́n ogbe ọkàn ni ikú èèyàn wa tó pàdánù èmi rẹ nínú igbó náà jẹ fún wa, ẹbi ologbe Michael Oyedokun lo fi edun ọkàn sọ̀rọ̀ sita bẹẹ * Bomo ẹni ba se re kawi, ẹgbẹ́ òsèlú APM gboriyin fun gomina ipinle Oyo ati awọn èso eleto ààbò fún itusile àwọn ọmọ tí wọ́n jí gbé ní ìpínlè Oyo * Ègbé oselu PDP àti Sowore tí kan saara sì gbogbo àwọn èso eleto abo to sise lai ṣáárẹ Lori itusile àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ati olukọ n'ilu Ogbomoso * Oluwo tí dá ayọ̀ rẹ pò mọ àwọn èèyàn ipinle Oyo fún itusile àwọn akẹ́kọ̀ọ́ lakata àwọn ajinigbe, Ọwá pé fún ìfọwọ́sowọ́pọ̀ tako ìṣòro abo larin àwọn oloselu * Makinde dúpẹ́ lọwọ Aare Tinubu, ó tún gbóríyìn fún àwọn èso alaabo fún ipa takuntakun wọn lórí itusile awon akẹ́kọ̀ọ́ láti ìgbèkùn àwọn ajinigbe * Lẹ́yìn wákàtí díẹ̀ tí mo kéde erongba mi láti díje dupo Aare orile-ede yii, yi ni wọ́n jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ati olukọ gbe nijoba ibile Oríre Gómìnà Makinde lo ṣàlàyé ọ̀rọ̀ bẹẹ Pipa àwọn ajinigbé tó ronúpìwàdà lòdì sí ẹ̀sìn àti òfin àgbáyé – Sheikh Gumi lo sọrọ bẹ pẹlu alaye * Nibo ni àwọn ajinigbe náà wá, nibo ni iṣẹlẹ naa ti ṣẹlẹ̀, efi àwòrán wọn hàn wá wonyi atawọn ìbéèrè míì lawọn ọmọ Naijiria ti ń béèrè lẹ́yìn itusile awon akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ ni ipinlẹ Oyo

MAKINDE FORUKO AWON EEYAN MARUN TO PADANU EMI WON LASIKO TI WON FE DOOLA AWON AKEKOO ORIIRE,OGBOMOSO

Muslim-Muslim Ticket: Many Christian Leaders Are Ignorant of Politics - Pastor Femi Emmanuel

Fake Agency: Those Officials Who Gave Wavers Need to Be Called to Testify Publicly- Jega /Mamedu

IYAAFIN ALAMU TU ASIRI OHUN OJU AWON OMO KEKEKE RI NI IGBEKUN AWON AJINIGBE KI WON TO RI ITUSILE GBA

The Morning Show: Lagos Celebrates Obaigbena At THISWEEK At 40

Israel, Messi and Argentina explained

'We Want Fulani Militia Out Of Our Land', Convener Save Benue Alliance Sues For Peace |Sunrise Daily

LÓRÍ OYÈ ATAYESE - ALÁÀFIN Ń BÍNÚ SÍ OLUWO

HA! AWON OMO YORUBA META TO GBABODE PELU AWON EEYAN META MIRAN TOWOTE…ASIRI BI WON SE RESCUE WON REE

HOW THE OYO CHILDREN WERE RESCUED!SUNDAY IGBOHO WON!CELEBRATING DR AMB ADEYEMI

C4 and Bryan Nehman react: Trump’s Speech on Election Integrity

BREAKING: Alao-Akala's Aide Fires Back at Gov. Makinde Over Abducted Oyo Teachers and Pupils

Discussing Oriire Rescue, Tinubu’s Muslim Muslim Ticket For 2027 +More | Morning Brief

JUST IN: Nick Shirley And James O'Keefe Testify Before The Senate Homeland Security Committee

ASIRI BI ASE GBENA WOJU AWON AJINIGBE TO JI AWON AKEEKO ATI OLUKO GBE - ILEESE OLOGUN SORO SOKE

SUNDAY IGBOHO TU ASIRI IDI TI IJOBA SE KO LATI SANWO ITUSILE AWON AKEKOO ATI OLUKO F'AWON AJINIGBE

RESCUED ORIRE VICTIMS REUNITE WITH FAMILIES, AS LAUTECH HOSPITAL DISCHARGE SOME OTHERS ON TREATMENT

/ NORTHERNER OFEGBA TINUBU FEDARU/OLU'WO FI VDM JOYE ORISHA NLA /KI MAKINDE RESIGNED BAWO?

AWON AJINIGBE YABO IJO C & S ATI TI REDEEM NI ALE OJO KAN,WON PA PAITO KAN WON SI JI AWON EYAN GBE

