KAARO OJIIRE

Ijiroro Owuro pelu Ola Onabajo ati awon alejo wa odomode akinkanju Ekundayo Taiwo ati kehinde aka Glorious Twins soro nipa ise Orin gege bi ise ti won yan laayo. Ni ojo aje titi di ojo aiku lori Startimes Channel 132, lagogo mesan titi di agogo mewa. E feran re, fi esi si, ki e si tun subscribu si www.kaftan.tv S' afojusun aye t'orewa