OLUWO TILU IWO WOJU AWON OLOOGUN TI WON MA LERI OGUN LATI LO KOJU AWON AJINIGBE AGBEBON NI NU IGBO

OLUWO TILU IWO WOJU AWON OLOOGUN TI WON MA LERI OGUN LATI LO KOJU AWON AJINIGBE AGBEBON NI NU IGBO Ìgbìnmọ́ Májékóbájé Ilé-Yorùbá ti kilo fun adájọ́ Umar lati túùkanna lẹ́yìn orun Sowore, tobá si ko lati sebe àwọn ó kọ̀wé sì àjò àgbáyé kí wọn gbèsè lè fisa rẹ Ao darapo mo ẹgbẹ́ Boko Haram pelu ife inú ara, agbára kàkà ni wọn fi mú wá láti darapo, ọmọ ẹgbẹ́ Boko Haram tó ronupiwada lọ ń bẹ àwọn ọmọ Naijiria fún ìdáríjì Àwọn ọmọ Naijiria bù ẹnu àtẹ lu aya Aare Tinubu pelu bose fi ọ̀rọ̀ ìkínni lédè layajo òjò àwọn ọmọde ni Afrika lai menu bá ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ tó wà nigbekun ni Naijiria Àwọn olùgbé ipinle Kwara mẹsan rí òmìnira gba lọwọ àwọn ajinigbe, àwọn agbofinro mú èèyàn mẹ́rìn to ń jí ẹrù àwọn èèyàn ní agbègbè tí àwọn agbesumomi sekolusi Òpó èèyàn ló ti padanu emi wọn lórí ọ̀rọ̀ àwọn ọmọ tí wọn jigbe, tó fi mọ Ogagun kan, tio bá ṣe pé kín fi èmi mi rúbọ nio mú àwọn ọmọ náà padà wálẹ̀ máa ṣe bẹ́ẹ̀. Gomina Makinde lọ sọ̀rọ̀ sita Ọrọ lo delẹ yi o, ẹyin tẹ ma n janu pe ẹ loogun, ẹ le soke dilẹ, awọn ọmọ wa nínú igbo ẹ o ri nkan se si. Oluwo lo ta awọn onisegun laya bẹ. Alaye re o lori awuyewuye to tun ṣuyọ lori pe se lóòótọ́ ni ìjọba àpapọ̀ ti sanwó ìjọba ìbílẹ̀ Osun tó di wahala. Ìdí e re o tí ilé ẹjọ́ kòtẹ́milọ́rùn fi ṣẹ́wélé àṣẹ ile ẹjo tó ní kí INEC yọ orúkọ ẹgbẹ́ òṣèlú Accord áti ADC O kúrò nínú àkọsílẹ̀ rẹ̀ Mo ní ilese nílé south Africa lọ́nà to bofinmu, mo gbà ọmọ ilé south Africa toto ọgbọ̀n sise, oníṣòwò ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà lọ sọ̀rọ̀ síta leyin tí wọn ní kofiile south Africa sile

Watch Till the End... I Can't Stop Laughing 😂 | Akpi, Odumeje, Germany Hospital Bed
▶︎

EYIN OMO YORUBA !  OMINIRA TI SU MOLE O ! ORO NLA RE O!

🔥BREAKING: Atiku To NDC? Peter Obi Under Pressure ✌️ As ADC Crisis Deepens, Sowore Blasts Tinubu! 😳

🔥 FINAL IGBOHO SET FOR RESCUE,AS YORUBA LAND UNDER SIEGE...GANI ADAMS .....

EMOTIONAL MOMENT!! 😭 BABA IJESHA’s Friends & Family Celebrate Him as IYABO OJO Finally Speaks After…

ORIYOMI HAMZAT ATI ADEMOLA ADELEKE FARAYA LORI IDAJO ILEJO LORI BI INEC SE FE YO ORUKO ACCORD KURO

Breaking: Nigerian Army Rescues 5 Kidnap Victims From Fulani Bandits in Kogi State

People like this are the reason why politicians think they are bigger than the masses that got the

FINALLY!! 😭 SOUN OGBOMOSO Gives Fresh Update as Soldiers Rescue Abductees, ADETOUN ONAJOBI, OONI IFE

UPDATE: ONA ABAYỌ KAN RE O! || FINALLY SOLUTION IS HERE || EVERYONE MUST HEAR THIS.

ORIYOMI HAMZAT TI FESI SI ESUN TI WON FIKAN LORI IBASEPO PELU AWON ADIGUNJALE TAWON OLOPA N WA

BOMBSHELL - SEYI MAKINDE KNEW ABOUT AHORO / ESHIELE K1DN@PPING

OWO AFEFE - Latest Yoruba Movie 2026 | Damilola Oni, Remi Surutu, Kunle Omisore, DivaGold, Mimmy Tea

OBA ZORO - SEGUN OGUNGBE  - Latest Yoruba Movies 2026 Yoruba Movie 2026 Drama

LORI AWON AKEKOO TI WON JIGBE L'OGBOMOSO EGBE OPC ATI AWON MI GBENA WOJU IJOBA IPINLE OYO

Jalo jalingo tsakanin dabarun tallata tinubu da kai iyayen Annabi wuta.

GOMINA ILE YORUBA YI TI PASE IGBESẸ TITUN BE NI ỌWỌ TI BA WON LAKURAWA

NIGERIA: Everyone Warned Us Not to Come
▶︎

NIGERIA: Everyone Warned Us Not to Come

KOKORO ALATE | IYAWO MI ATI ALE LO FOMI L'OJU OO.#viralvideo

Can 5 IGBOS find the 2 secret YORUBAS Amongst Them?