E ba wa yin Oluwa, Hallelujah - Latest Yoruba 2022 Movie and Song

Latest Yoruba Song and Movie *winks from Bisimanuel and Heeyarhnu E ba wa yin Oluwa, Hallelujah - Latest Yoruba 2022 Movie and Song Eni t'O f'orun sile t'O wa s'aye Lati ku fun ese araye gbogbo; E korin aleluya s'Oba mimo Eni ba more Jesu ko ba wa gbe ga. Eni t'O pa wa mo o lojojumo, Eni t'O n yo wa ninu ewu gbogbo Eni t'O n pa Israeli mo k'itogbe Eni ba more Jesu ko ba wa gbe ga. Powerful Lyrics, Powerful Words, Enjoy. #latestnews #yorubamovies #bisimanuel