ASIRI IKU TO PA OLORI NIGERIA IGBAKANRI ABACHA TU SAYE - ORI OBINRIN LO KU SI DENNIS TU PEREPERE ORO

ASIRI IKU TO PA OLORI NIGERIA IGBAKANRI ABACHA TU SAYE - ORI OBINRIN LO KU SI DENNIS TU PEREPERE ORO Ero awọn Oba sotooto o lori idasile lọ́balọ́ba lẹ́kùn ìdìbò Ìwọ̀ oòrùn Osun ti won fi Oluwo se alága láéláé rẹ Ileṣẹ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Bauchi ti mú ọkùnrin kan leyin ti wọn lo fi ìbọn ibile gbemi olórí Àdúgbo kan ni ipinlẹ naa Ẹgbẹ́ òṣèlú AAC ni ipinlẹ Osun tí kesi oga agba ọlọ́pàá Naijiria láti paro kọmiṣọna ọlọpaa ipinlẹ naa nítorí ohun tí wọ́n pé ní ainigbokanle nínú rẹ̀ mọ Abacha pana nítorí ọkàn rẹ tó dase sílẹ̀ lakoko ibalopo pẹ̀lú obìnrin kan, kii se apple òní mojele lọ paa, Dennis Amachreelo ṣàlàyé bee Àwọn ajinigbe to jí àgbẹ́ méjì gbé ní ìpínlè Ondo tí ń bèerè milionu mewa kí wọ́n to tú àwọn tí wọ́n jigbe sílẹ̀, ilese ọlọ́pàá bèrè igbésẹ̀ idoola Atiku tí kesi Ààrẹ Tinubu láti tọrọ ìdáríjì lọ́wọ́ gbogbo àwọn ọmọ Nàìjíríà, kosi fi ipò sílẹ̀ pelu bí ẹsẹ̀ isejoba rẹ àti àwọn Ileṣẹ tó wà lábé rẹ ṣe ń ṣe ségesège Oga agba ọlọ́pàá orile-ede Naijiria ti kesi àwọn ọlọpaa láti yara fún àwọn ìwà tí kò bófin mú, oro awon kọmiṣọna láti yẹra fún títí aláìṣẹ̀ mole àti gbigba ọwọ́ tí koto ‎ - Ààrẹ Tinubu tí buwọlu dídá ibùdó ológun míì sílẹ̀ ní Ọmú-Aràn, ní ipinle Kwara láti le kojú ìjínigbé àti ìkọlù àwọn agbébọn CBN salaye ẹni tó pàṣẹ pé kí wọn ṣí àkáǹtì fún ayédèrú iléeṣẹ́ PFIPC lábẹ́ Adeniyi Adeyemi, bí Gbajabiamila ṣe ń rojọ́ níwájú àjọ ICPC Ileṣẹ Ọlọ́pàá Ìpínlẹ̀ Osun tí mú àwọn jànduku àdàlú ru, ọmọ isota olóṣèlú, àti igara olosa nínú ìsapá won láti dá àláfíà padà sí ipinle Osun Wọ́n ti tu DJ Chicken sílẹ̀ o lẹ́yìn tó tele àwọn ìlànà béèlì rẹ̀