EYIN OBA OGO

Eyin Oba ogo, On ni Olorun Eyin Oba ogo, On ni Olorun Yin fun 'se 'yanu ti o ti fihan O wa pelu awon ero mimo l'ona O si je imole won l'osan l'oru. E yin Angel 'didan, lu duru wura Ki gbogbo yin juba, t'e now oju re Ni gbogbo 'joba re, b'aye ti nyi lo Ise re y'o ma yin Ise re y'o ma yin Fi ibukun fun Oluwa okan mi. E yin fun 'rapada ti gbogbo okan E yin fun orisun imularada Fun inu rere ati itoju re Fun 'daniloju pe O ngbo adura, E yin fun idanwo bi okun ife, T'o nso wa po moa won ohun orun Fun 'gbagbo ti n|”segun , 'reti ti ki sa Fun ile ogo t'O ti pese fun wa.