CCC HYMN 276 - E BA WA YO ARA NINU KRISTI | YORUBA
CCC HYMN 276 YORUBA 1. E ba wa yo, ara ninu Kristi, Fun o ri rere ta ni, Wakati buburu na de, Ti o mu aiye yi gbona, Elese ronupiwada, Ni ‘jo Mimo yi. 2. Ogbun nla si sile nisisiyi, Lati t’eruku jade, Bo ko ba fe jeni egbe, Si odo Olugbala Re, Ro mo Kristi ‘nu Ijo Mimo yi, Yio ran o lowo. 3. Laipe, Baba ki yio mo omo, Tab’omo mo Baba re, K’aiye sile sa to Kristi, O duro loke mimo Re, Rukerudo ‘parun nla mbo, Ya ronupiwada. 4. Mo si tun nduro ninu anu mi, Npe awon elese, Wakati yi e pawada, Laipe anu yio dopin, Fi ‘ka, aje, orisa sile, Kristi yio, gba wa la. 5. Gbogbo ekun aiye ti se simi, Sibe nko bikita, Nko ro ewa ti Orun, Kika ni irun ori yin, Lomu Emi Kristi jiya na, Emi ni, wa, ki o ye. 6. Niti iparun ti aiye yi, Mo fi anu fa se yin Sibe aigbagbo nposi, Nwon nsin orisa, aje, Nwon lo arakan ati ika, fi won le wa ‘do Mi. 7. Mo ti pese ohun rere fun o, Ade didan iye na, Bugbe re nduro de o, Lori ile didara na, F’aiye sile, wa wa sodo mi, Emi o tewo gba o. Amin

Orin 276 (E ba wa yo, ara ninu Kristi)

Hymn 406 - 43rd Adult Harvest

CELESTIAL OLDIES MEDLEY WITH ARINOLAMI #oldies #oldiessongs #evergreen #celestial #ccc #oldsong

CCC Hymns are divine! CCC Hymn 276 E ba wa yo ara ninu kristi

CCC HYMN 77 - ORUN, OSUPA, IMOLE, IRAWO

Hymn 276 - 43rd Adult Harvest

2025 EASTER SERMON

Mo Ti Ni JESU Lore by OreOluwa EniObanke Brown ft Eniola Bello

El Beracad Bered Eli - CCC Hymn 426

Hymn 694 - "Ka Sise Fun Iwenumo Emi Wa" - Adult Harvest 2021

ORO RE! IGBOHO TI DE NIGER STATE O - ALAYE NIPA ORO ILE YORUBA ATI SUNDAY IGBOHO OOSA

CCC HYMN 276 (Ẹ ba wa yọ, ara ninu Kristi) With Lyrics

CCC Hymn 773 (Ka Sowo Po, Ka Sowo Po) by CELEFUTA

Harjovy IRAWO Lyrics Video

Ô ry Jesoa mofo velona_Hira Katolika Malagasy

41st Adult Harvest 2017 - Hymn 580 - "Nigbati Fere Oluwa Yio Dun"

CCC Hymn 276 with lyrics || CCC Calgary Model Parish #ccc #celestial #hymns #songs #song #music

NAIRA MARLEY TU ASIRI OUN ORO IKU SAMALARRY TI WON GBE KIRI BAYI...QUADRI HAMZAT REPORTING

CCC Hymn 426 - El Berecah Bered Eli

