ASIRI AWON OLOSELU TO WA LEYIN IJINIGBE TO SELE NILU OGBOMOSO MA TU SAYE SUNDAY IGBOHO LO SORO BEE

ASIRI AWON OLOSELU TO WA LEYIN IJINIGBE TO SELE NILU OGBOMOSO MA TU SAYE SUNDAY IGBOHO LO SORO BEE O lagbara o, Billionu kan Naira, òhun ijagun, ọkọ Hilux ati sise atunse si awọn ofin kan lọna ti o sègbè̀ lẹyin awọn agbébọn lohun tawọn ajínigbé n béèrè lọwo Ìjọba ki won o to tu awọn akẹkọọ áti oluko to wa lahamo wọn silẹ, ẹ gbo ṣekijọba o fun wọn. Ikunlẹ Abiyamọ o, Àwọn Olùjọsìn to jẹ jijigbe salọ ni Ṣọọṣi ECWA nipinlẹ Kwara ku s'igbèkùn awọn Ajinigbe-Agbebọn Tí ò ba lọwọ ń nù ni, wọn ò bá jẹki ń lọ koju àwọn ajínigbé, tí wọ́n ó bá sì tete gbé ìgbésẹ láti doola àwọn ọmọ tí wọn jì gbé Ma ka orúkọ àwọn oloselu to lọwọ nínú iṣẹlẹ ijínigbé to wáyé nipínlè Oyo - Sunday Igboho lo sọrọ soke bẹẹ Àwọn Aṣofin ipinlẹ Ọ̀yọ́ kọ igbesẹ idunadura pẹlu awọn Ajinigbe, wọn bèèrè fún itusilẹ-ominira awọn Olufarakasa Irọ to jinna sootọ nipe awọn akẹkọọ at'olukọ to wa lahamọ awọn ajínigbé ti gbà ominira o, kẹ ye tẹti siroyin ofege ti wọn gbé kiri. Lori iṣẹlẹ ijinigbe to waye nipinlẹ Ọyọ: Ti ẹ ba gbe ìgbésẹ láti pa awọn Àgbèsúnmọmi naa run, O le yọrí sí pipa awọn ọmọde to wà níbẹ run - Akpabio lo sekilọ bẹẹ Haa! Àwọn Ọkùnrin mẹjọ fi tipa ba ọmọdebinrin ọmọ ọdún mẹrindinlogun 16 lajọsepọ nipinlẹ Anambra Ni kanmọ nkobo, ẹ yara tete doola awọn Ọmọ ọlọmọ ti wọn wa nigbekun awọn ajínigbé, ẹ tete yanju ẹ láàrin ara yin - Saheed Osupa lo sọ fun Ìjọba bẹẹ. Àwọn agbebon ṣekọlu sì Alága Ẹgbẹ́ oselu Accord Party, Asimiyu Ajibola ní Ìjọba Ìbílẹ̀ Osogbo, ní Ìpínlẹ̀ Osun. Ajọ panapana yọ òkú ọkùnrin kan tó ku sínú kànga lakoko to ń gbìyànjú láti yọ fóònù rẹ tó bọ sinu kànga nipinlẹ kano

Masoyinbo || Episode Three Hundred and Ten with Muyideen Oladapo (LALA): An exciting game show
▶︎

EMU  MAKINDE DAADA /     FULANI KISEFAMILY E
▶︎

EMU MAKINDE DAADA / FULANI KISEFAMILY E

SEKUPA GBOGBO AWON AGBESUNMOMI TABI KO KOWE FIPO SILE - ADEBAYO GBENAWOJU TINUBU

LATEST & TRENDING NEWS FOR THE DAY...IROYIN AKOJOPO AGBEYEWO LORI YBN..NIGERIA & YORUBA NATION NEWS

ASIRI TU O!! ORIYOMI HAMZAT TI PADA SORO LORI BI GUNMI SE WA SI ILU IBADAN ATI AWON ASIRI TO ROMO

KISE FULANI LO KOWON LOYO YORUBA NI - NORTHERNER/ KI DSS GBE IGBOHO TORI KINI? /SADE TINUBU  BINUTAN

Asiri Agbara Awon Baba Wa!!!
▶︎

Asiri Agbara Awon Baba Wa!!!

OPE O!! 😭 Bandit Surrender as Many Arrested, SAHEED OSUPA, WASIU AYINDE, KOLA OLOOTU, VERYDARKMAN 💔

MYSTERY! THE SACRED SECRET OF IGBO OLOKUN THAT STILL HAUNTS MANY&THE HIDDEN LINK TO THE OONI'S CROWN

ÀWỌN ÀTÍKÙ TI GBÉ ÌJÀ NLA LỌ SỌ́DỌ̀ PETER OBI NÍNÚ NDC, WỌ́N NÍ KÒ LÈ DUPÒ ÀÀRẸ

ORI ABURO MI TI WON GE N DA MI LAAMU - EGBON OLUKO TI AWON AGBESUNMOMI PA L'OGBOMOSO LO KOMINU BEE

OGUN DÉ É - 8 SOLDIERS B3AHED3D BY B@NDIT TODAY - 05/06/2026

Ghana Just Made A HISTORIC Move To Retaliate South Africa’s Xenophobia

LAST CALL ON THE AUTHORITY , EGBA IGBOHO LAYE EJE KOBA WA GBA AWON OMOWA SILE OO!!

Gov Abiodun's Aide Fires Back At Gbenga Daniel, Describes Ex-Gov's Claims As Untrue

ORO BA SE MA RESCUE AWON TI WON JIGBR…IGBOHO VS GOV. MAKINDE….THIS PEOPLE ARE SO WÍĆK£D!!!

DSS must invite Igboho-Atiku Aides|Two Tiktok B%ndits reportedly arrested|Seyi Makinde bans Okada...

E FI GBOORO OFIN GBE AHMAD GUMI KIAMOSA LORI ESUN IKEDUN FUN AWON AGBEBON - ADEYANJU LO SORO SOKE BE

Obi's Move To PRP Failed Over Presidential Ticket Guarantees, Slot Demands - Chairman

ASIRI SEYI MAKINDE TU. AWON AGBESUMOMI TI TU ASIRI NLA JADE NIPA ADEHUN WON PELU MAKINDE