SUNDAY IGBOHO TI JADE SORO LORI ITUSILE AWON TI WON JIGBE NI ORIIRE, OGBOMOSO O KAN SARA SI IJOBA
SUNDAY IGBOHO TI JADE SORO LORI ITUSILE AWON TI WON JIGBE NI ORIIRE, OGBOMOSO O KAN SARA SI IJOBA Sunday Igboho juwo kaare sì Ààrẹ Tinubu àti àwọn ẹka ààbò fún ìṣe takuntakun wọn lórí itusile àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ìpínlè Oyo Báyọ̀ Onánúgà gbéna woju Atiku fún bí ó ṣe dákẹ́ tí ó si fi kini ranse látìgbà tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ ipinle Oyo ti gba ominira, pelu gbogbo ariwisi ṣáájú itusile naa - Itusile àwọn ọmọ ilewe ìpínlè Oyo leyin òjò marundinlogata tí fi aikoju òṣùwò̩n ijoba Aarẹ Tinubu hàn, Francis Nwapa lọ sọ̀rọ̀ síta bẹẹ - Kò yẹ kí ọmọ Naijiria kánkán má ni ìrírí ijinigbe pàápàá julọ ni ile eko, Peter Obi ni itusile àwọn ọmọ ilewe ipinlẹ Oyo tú àṣírí àìsí ààbò lorilẹede yii - Atiku soko ọ̀rọ̀ padà sí ilé ṣe Ààrẹ pelu bí ose ni kenu má gbofo ni ọ̀rọ̀ tí wọ́n sọ pé òun ó fé sì sí itusile àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ipinlẹ Oyo - Lẹyin itusile àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ipinle Oyo, sultan ṣòkòtò fi ayo rẹ, o wa pé fún itusile àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ipinle Borno - Sunday Igboho juwo kaare sì Ààrẹ Tinubu àti àwọn ẹka ààbò fún ìṣe takuntakun wọn lórí itusile àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ìpínlè Oyo Itusile àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ipinlẹ Oyo fi hàn pé àwọn ọmọ ògùn wá koju osunwon tí wọ́n bá rí atileyin tótó, Gbenga Olawepo Hashim lọ sọ̀rọ̀ nígbà tó ń kí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ naa - Remi Tinubu sọ̀rọ̀ ṣègbé àkàrà, agbado sísun àti kulikuli tita, ó kesi Davido àti àwọn odò leka amuludun láti máa ṣèrànwọ́ fún àwọn aláìní

Oriire Rescue: Watch the moment Gov. Seyi Makinde receives the students and teachers at the Office

ASIRI BI ASE GBENA WOJU AWON AJINIGBE TO JI AWON AKEEKO ATI OLUKO GBE - ILEESE OLOGUN SORO SOKE

MAMA PRINCIPAL SALAYE OHUN TAWON T£ŘŘØŘÌŚT TO JIGBE FOJU WON RI ATI BI WON SE PA OLUKO MIRAN DEACON

Friends turned foes: The split reshaping Senegal | Talk to Al Jazeera

HOW THE OYO CHILDREN WERE RESCUED!SUNDAY IGBOHO WON!CELEBRATING DR AMB ADEYEMI

OTUN TI SELE OO! LORI ORO AWON OMO ILEWE OGBOMOSHO, OHUN TOTUN SELE REE!!

FINALLY!! 😳 Names of Alleged Informants in Oriire Kidnap Exposed, ORIYOMI HAMZAT Tu Perepeere

HAHAHA! HAMZAT OTA ILE YORUBA! EWAGBO OOO!!

ASIRI AWON TO WA NI DI IJINIGBE AWON AKEKO ATI OLUKO L'OGBOMOSO TI TU- KOLA OLOOTU TU PEREPERE ORO

BREAKING: Alao-Akala's Aide Fires Back at Gov. Makinde Over Abducted Oyo Teachers and Pupils

HA! NKAN DE!! WON TUN JI HEADMASTER GBE…OTITO ORO PONBELE LORI ORO BI WON SE RESCUE, IKU LT ISAAC…

O pari! Tinubu daruko awon to ji awon akekoo ati oluko n'iluu Ogbomoso

PRINCIPAL ILE IWE ORIIRE TI SORO O. EWAGBO OHUN TOSELE SI AWON OMO ILE IWE LOWO AWON AGBESUMOMI.

WHERE'S JOHN OLALEYE ONE OF THE ABDVCTED TEACHERS IN ORIIRE

IPA IGBOHO LORI RESCUE AWON EEYAN NI ORIIRE..AWON OLOGUN TO PADANU EMI WON..VIDEO OPERATIONS ORIIRE

😭 Emotional Moment Husband of Esiele Principal Rescued Couldn’t Hide His Joy & Award

IYAWO GOV. SEYI MAKINDE FI ESUN KAN OKO RE NINU ORO GBIGBE AWON AKEKO ATI OLUKO?

AṢIRI NLA! EYI NI ỌGBỌN TAWỌN OLOGUN FI FẸYIN AWỌN AFẸMIṢOFO YII BALẸ

WON TI GBE GANI ADAMS SI TA GBA GBA

