
▶︎
IWINLE GBE AGBONRIN TI MO PA WO INU OKITI OGAN, GBOGBO AGBARA LAA SA.

▶︎
IGBO IFA IGBO TO BURU NI,BAA BA TI DE'BE, EYE KAN MAA KE, GBOGBO ERANKO MAA DI OJU NI.

▶︎
ADIYE FUNFUN REPETE NI MO RI NINU IGBO LAARIN ORU, MI O RI IRU RE RI.

▶︎
AGBONRIN TI AJA MI MU, EJO LO YO JADE NI IMU RE, A O RI EJO NAA PA

▶︎
IGALA ABAMI TI MO PA, BAA TI N KUN ERAN NI ERAN N SHOCK WA BI INA .

▶︎
KEHINDE ASIPA TAA JO SODE KO JADE NINU IGBO ,NI IPADE BA DEBA GBOGBO ODE

▶︎
MO BA EWURE ABAMI NI ODO TO NFO ASO LAARIN ORU, O NI KI N PADA S'ABULE.

▶︎
BABA MI FE FI OBE DU OLUFA NI ERAN BA YARI, EJO OLUFA BINU, O LO MO BABA MI.

▶︎
ANJONNU IYA AGBA KAN WAA BAWA NI ILEBA, O BEERE TABA ATI IFINMU,LESEKESE LO POORA

▶︎
EEWO NI, ODE KO GBODO PA ODO MOSIA, ODE TO BA PA OMO MOSIA , YOO KU .

▶︎
OJO TI EJO OLUFA FI ARA RE HAN MI, NI OJO TI MI O LEE GBAGBE LAELAE.

▶︎
OKU LAA BA LAARIN ORU, TO SUN SINU OJO, ASE ACCIDENT KAN SELE NI YAJOYAJO NI.

▶︎
IWIN IGI OSHE GBE ERAN ETA TI MO YINBON SI, IJONGBON SELE

▶︎
WHITE HANKERCHIEF NI MO BA NINU ETU, OUN NI MO FI NWO ISE .

▶︎
IYAWO KAN NI MO NI,SUGBON ERAN PIPA TI JE KI N NI ALE REPETE. OBINRIN FERAN ERAN

▶︎
